ORIN DAFIDI 69:33

ORIN DAFIDI 69:33 YCE

Nítorí OLUWA a máa gbọ́ ti àwọn aláìní, kì í sìí kẹ́gàn àwọn eniyan rẹ̀ tí ó wà ní ìgbèkùn.