ORIN DAFIDI 73:26

ORIN DAFIDI 73:26 YCE

Àárẹ̀ lè mú ara ati ẹ̀mí mi, ṣugbọn Ọlọrun ni agbára ẹ̀mí mi, ati ìpín mi títí lae.