ORIN DAFIDI 98:4

ORIN DAFIDI 98:4 YCE

Gbogbo ayé, ẹ hó ìhó ayọ̀ sí OLUWA; ẹ bú sí orin ayọ̀, kí ẹ sì kọ orin ìyìn.