ORIN SOLOMONI 3:1

ORIN SOLOMONI 3:1 YCE

Mo wá ẹni tí ọkàn mi fẹ́, lórí ibùsùn mi lálẹ́, mo wá a, ṣugbọn n kò rí i; mo pè é, ṣugbọn kò dáhùn.