Gbé mi lé oókan àyà rẹ bí èdìdì ìfẹ́, bí èdìdì, ní apá rẹ; nítorí ìfẹ́ lágbára bí ikú. Owú jíjẹ burú, àfi bí isà òkú. A máa jó bí iná, bí ọwọ́ iná tí ó lágbára.
Kà ORIN SOLOMONI 8
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN SOLOMONI 8:6
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò