I. A. Ọba 19:6

I. A. Ọba 19:6 YBCV

O si wò, si kiyesi i, àkara ti a din lori ẹyin iná, ati orù-omi lẹba ori rẹ̀: o si jẹ, o si mu, o si tun dùbulẹ.