II. A. Ọba 2:1

II. A. Ọba 2:1 YBCV

O si ṣe, nigbati Oluwa nfẹ lati fi ãjà gbé Elijah lọ si òke ọrun, ni Elijah ati Eliṣa lọ kuro ni Gilgali.