II. Sam 24:25
II. Sam 24:25 YBCV
Dafidi si tẹ́ pẹpẹ kan nibẹ si Oluwa, o si rú ẹbọ sisun ati ti ìlaja. Oluwa si gbọ́ ẹbẹ fun ilẹ na, arùn na si da kuro ni Ìsraeli.