O. Daf 97:9

O. Daf 97:9 YBCV

Nitoripe Iwọ Oluwa, li o ga jù gbogbo aiye lọ: Iwọ li a gbé ga jù gbogbo oriṣa lọ.