Y-vio Dios --todo-que hizo y-mira-buena muy y-fue-tarde y-fue-mañana día sexto. -
Kà Gen 1
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Gen 1:31
3 Awọn ọjọ
Gbogbo olùpèsè-ọjà ló ní èrèdí fún pípèsè ọjà kọ̀ọ̀kan. Ọlọrun dá ẹnìkọ̀ọ̀kan fún ètò àti ìlànà pàtàkì kan. Èrèdí ìgbélé-ayé ni kí á rí i dájú pé a gbé ìgbésí ayé wa láti jẹ́ kí èrèdí yìí wá sí ìmúṣẹ. Ẹkọ yìí dù láti wa àwàjinlẹ̀ lórí kókó-ọ̀rọ̀ náà.
7 Days
Ready to grow as a leader? Craig Groeschel unpacks six biblical steps anyone can take to become a better leader. Discover a discipline to start, courage to stop, a person to empower, a system to create, a relationship to initiate, and the risk you need to take.
7 Ọjọ
Bawo ni gbogbo rẹ ṣe bẹrẹ? Nibo ni a ti wa? Kini idi ti irora pupọ wa ni agbaye? Ṣe ireti eyikeyi wa? Njẹ aye wa lẹhin ikú? Wa awọn idahun bi o ti ka itan otitọ yii ti aiye.
Ìrìnàjò ẹ̀dá dé kọ́ọ̀sì, tí ń ṣàfihàn bí ìfẹ́ Ọlọ́run ti ń tọ́ ènìyàn láti ìbẹ̀rẹ̀. Bí ènìyàn ṣe ṣubú, bee ọkàn Ọlọ́run kò yí padà, ẹ̀tò ìràpadà rẹ̀ wà nípò, látàrí Jesu Kristi.
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!