1 Ọba 17:14

1 Ọba 17:14 YCB

Nítorí báyìí ni OLúWA Ọlọ́run Israẹli wí: ‘Ìkòkò ìyẹ̀fun náà kì yóò ṣófo, bẹ́ẹ̀ ni kólòbó òróró náà kì yóò gbẹ, títí di ọjọ́ tí OLúWA yóò rọ òjò sí orí ilẹ̀.’ ”