Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

1 Ọba 3:7

1 Ọba 3:7 BMYO

“Nísinsin yìí, Olúwa Ọlọ́run mi, o ti mú ìránṣẹ́ rẹ jẹ ọba ní ipò Dafidi baba mi. Ṣùgbọ́n ọmọ kékeré ni mí, èmi kò sì mọ jíjáde àti wíwọlé mi.