2 Kronika 19:7

2 Kronika 19:7 YCB

Nísinsin yìí jẹ́ kí ìbẹ̀rù OLúWA kí ó wá sí ọkàn rẹ̀. Ṣe ìdájọ́ pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, nítorí pẹ̀lú OLúWA Ọlọ́run kò sí àìṣedéédéé tàbí ojúsàájú tàbí gbígba àbẹ̀tẹ́lẹ̀.”