Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

2 Ọba 19:19

2 Ọba 19:19 BMYO

Nísinsin yìí Olúwa Ọlọ́run wa, gbà wá kúrò lọ́wọ́ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn ìjọba lórí ilẹ̀ ayé le mọ̀ pé ìwọ nìkan ṣoṣo ni, Olúwa Ọlọ́run wa.”