Ìṣe àwọn Aposteli 15:11

Ìṣe àwọn Aposteli 15:11 YCB

Ṣùgbọ́n àwa gbàgbọ́ pé nípa oore-ọ̀fẹ́ Olúwa Jesu àwa ó là, gẹ́gẹ́ bí àwọn.”