Ìṣe àwọn Aposteli 2:20

Ìṣe àwọn Aposteli 2:20 YCB

A ó sọ oòrùn di òkùnkùn, àti òṣùpá di ẹ̀jẹ̀, kí ọjọ́ ńlá àti ọjọ́ ológo Olúwa tó dé.