Deuteronomi 22:5

Deuteronomi 22:5 YCB

Obìnrin kò gbọdọ̀ wọ aṣọ ọkùnrin, tàbí kí ọkùnrin wọ aṣọ obìnrin, nítorí OLúWA Ọlọ́run rẹ kórìíra ẹnikẹ́ni tí ó ṣe èyí.