Eksodu 32:30

Eksodu 32:30 YCB

Ní ọjọ́ kejì Mose sọ fún àwọn ènìyàn náà pé, “Ẹ̀yin ti dá ẹ̀ṣẹ̀ tí ó pọ̀. Ṣùgbọ́n nísinsin yìí èmi yóò gòkè lọ bá OLúWA; bóyá èmi lè ṣe ètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ yín.”