Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Esekiẹli 22:31

Esekiẹli 22:31 BMYO

Nítorí náà ni mo ṣe da ìbínú mi sí wọn lórí, mo ti fi iná ìbínú mi run wọn, mo si ti fi ọ̀nà wọn gbẹ̀san lórí ara wọn, ní OlúwaOlódùmarè wí.”