Gẹnẹsisi 21:1-2

Gẹnẹsisi 21:1-2 YCB

OLúWA sì bẹ Sara wò bí ó ti wí, OLúWA sì ṣe fún Sara gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣèlérí. Sara sì lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan fún Abrahamu ní ọjọ́ ogbó rẹ̀, ní àkókò náà gan an tí Ọlọ́run ti ṣèlérí fún un.