Hosea 1:2

Hosea 1:2 YCB

Nígbà tí OLúWA bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ̀rọ̀ láti ẹnu Hosea, OLúWA wí fún un pé, “Lọ, fẹ́ àgbèrè obìnrin kan fún ara rẹ, kí ó sì bí ọmọ àgbèrè fún ọ nípasẹ̀ àwọn ọkùnrin mìíràn, nítorí ilẹ̀ ti ṣẹ ẹ̀ṣẹ̀ àgbèrè púpọ̀ nípa yíyapa kúrò lọ́dọ̀ OLúWA.”