Isaiah 12:1

Isaiah 12:1 YCB

Ní ọjọ́ náà ni ìwọ ó wí pé: “Èmi ó yìn ọ́, OLúWA. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé ò ti bínú sí mi ìbínú rẹ ti yí kúrò níbẹ̀ ìwọ sì ti tù mí nínú.