Isaiah 12:4

Isaiah 12:4 YCB

Ní ọjọ́ náà, ìwọ yóò wí pé: “Fi ọpẹ́ fún OLúWA, ké pe orúkọ rẹ̀, Jẹ́ kí ó di mí mọ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ohun tí ó ti ṣe kí o sì kéde pé a ti gbé orúkọ rẹ̀ ga.