Isaiah 36:7

Isaiah 36:7 YCB

Bí o bá sì sọ fún mi pé, “Àwa gbẹ́kẹ̀lé OLúWA Ọlọ́run wa,” kì í ṣe òun ni Hesekiah ti mú àwọn ibi gíga àti pẹpẹ rẹ̀ kúrò, tí ó sì wí fún Juda àti Jerusalẹmu pé, “Ẹ̀yin gbọdọ̀ sìn níwájú pẹpẹ yìí”?