Isaiah 45:2

Isaiah 45:2 YCB

Èmi yóò lọ síwájú rẹ èmi ó sì tẹ́ àwọn òkè ńlá pẹrẹsẹ Èmi yóò fọ gbogbo ẹnu-ọ̀nà idẹ èmi ó sì gé ọ̀pá irin.