Isaiah 45:4

Isaiah 45:4 YCB

Nítorí Jakọbu ìránṣẹ́ mi àti Israẹli ẹni tí mo yàn Mo pè ọ́ pẹ̀lú orúkọ rẹ, mo sì gbé oyè kan kà ọ́ lórí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìwọ kò gbà mí.