Isaiah 6:3

Isaiah 6:3 YCB

Wọ́n sì ń kọ sí ara wọn wí pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun gbogbo ayé kún fún ògo rẹ̀.”