Jeremiah 1:11-12

Jeremiah 1:11-12 YCB

Ọ̀rọ̀ OLúWA sì tọ mí wá wí pé: “Kí ni o rí Jeremiah?” Mo sì dáhùn wí pé “Mo rí ẹ̀ka igi almondi.” OLúWA sì wí fún mi pé, “Ó ti rí i bí ó ṣe yẹ, nítorí pé mo ti ń ṣọ láti rí i pé ọ̀rọ̀ mi wá sí ìmúṣẹ.”