Jeremiah 8:9

Jeremiah 8:9 YCB

Ojú yóò ti àwọn ọlọ́gbọ́n, a ó dà wọ́n láàmú, wọn yóò sì kó sí ìgbèkùn. Nítorí wọ́n ti kọ ọ̀rọ̀ OLúWA. Irú ọgbọ́n wo ló kù tí wọ́n ní?