Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Joẹli 2:32

Joẹli 2:32 BMYO

Yóò sí ṣe, ẹnikẹ́ni tí ó ba ké pè orúkọ Olúwa ní a ó gbàlà, nítorí ní òkè Sioni àti ní Jerusalẹmu ní ìgbàlà yóò gbé wà, bí Olúwa ti wí, àti nínú àwọn ìyókù tí Olúwayóò pè.