Joṣua 4:24

Joṣua 4:24 YCB

Ó ṣe èyí kí gbogbo ayé lè mọ̀ pé ọwọ́ OLúWA ní agbára, àti kí ẹ̀yin kí ó lè máa bẹ̀rù OLúWA Ọlọ́run yín ní ìgbà gbogbo.”