Lefitiku 10:3
Lefitiku 10:3 BMYO
Mose sì sọ fún Aaroni pé, “Ohun tí OLúWA ń sọ nípa rẹ̀ nìyìí nígbà tó wí pé, “ ‘Ní àárín àwọn tó súnmọ́ mi, Èmi yóò fi ara mi hàn ní mímọ́ ojú gbogbo ènìyàn Ní a ó ti bu ọlá fún mi.’ ” Aaroni sì dákẹ́.