Numeri 14:9

Numeri 14:9 YCB

Ṣùgbọ́n ẹ má ṣe ṣọ̀tẹ̀ sí OLúWA. Kí ẹ sì má bẹ̀rù àwọn ènìyàn ìlú náà, nítorí pé a ó gbé wọn mì, ààbò wọn ti fi wọ́n sílẹ̀, OLúWA sì wà pẹ̀lú àwa, Ẹ má ṣe bẹ̀rù wọn.”