Òwe 14:26

Òwe 14:26 YCB

Nínú ìbẹ̀rù OLúWA ni ìgbẹ́kẹ̀lé tí ó lágbára, yóò sì tún jẹ́ ibi ààbò fún àwọn ọmọ rẹ̀.