Sekariah 1:3
Sekariah 1:3 BMYO
Nítorí náà sọ fún àwọn ènìyàn. Èyí ni ohun tí OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí: ‘Ẹ padà sí ọ̀dọ̀ mi,’ báyìí ní OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí, ‘èmi náà yóò sì padà sí ọ̀dọ̀ yín,’ ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí.