Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 16:10YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ ma ṣogo li orukọ rẹ̀ mimọ́; jẹ ki ọkàn awọn ti nwá Oluwa ki o yọ̀.
I. Kro 16:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìyìn nínú orúkọ rẹ̀ mímọ́; jẹ kí ọkàn àwọn tí ó yin OLúWA kí ó yọ̀.
I. Kro 16:10YCE(Yoruba Bible)
Ẹ máa fi orúkọ rẹ̀ ṣògo, kí ọkàn àwọn tí wọn ń sin OLUWA kún fún ayọ̀.
Pín
I. Kro 16YCE