Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 16:15YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ ma ṣe iranti majẹmu rẹ̀ titi lai, ọ̀rọ ti o ti pa li aṣẹ fun ẹgbẹrun iran
I. Kro 16:15BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó rántí májẹ̀mú rẹ̀ láéláé, ọ̀rọ̀ tí ó pàṣẹ, fún ẹgbẹẹgbẹ̀rún ìran
I. Kro 16:15YCE(Yoruba Bible)
Kò ní í gbàgbé majẹmu rẹ̀ títí lae, àní àwọn ohun tí ó ti pa láṣẹ láti ṣe fún ẹgbẹẹgbẹrun ìran
Pín
I. Kro 16YCE