Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 16:24YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ sọ̀rọ ogo rẹ̀ ninu awọn keferi; ati iṣẹ-iyanu rẹ̀ ninu gbogbo enia.
I. Kro 16:24BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kéde ògo à rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ohun ìyàlẹ́nu tí ó ṣe láàrín gbogbo ènìyàn.
I. Kro 16:24YCE(Yoruba Bible)
Ẹ kéde ògo rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ polongo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan!
Pín
I. Kro 16YCE