Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 16:25YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori titobi li Oluwa, o si ni iyìn gidigidi: on li o si ni ibẹ̀ru jù gbogbo oriṣa lọ.
I. Kro 16:25BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí títóbi ni OLúWA òun sì ni ìyìn yẹ jùlọ; òun ni kí a bẹ̀rù ju gbogbo àwọn Ọlọ́run lọ.
I. Kro 16:25YCE(Yoruba Bible)
OLUWA tóbi, ìyìn tọ́ sí i lọpọlọpọ ó sì yẹ kí á bọ̀wọ̀ fún un ju gbogbo àwọn oriṣa lọ.
Pín
I. Kro 16YCE