Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 16:26YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori pe gbogbo oriṣa awọn enia, ere ni nwọ́n: ṣugbọn Oluwa li o da awọn ọrun.
I. Kro 16:26BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí gbogbo àwọn ọlọ́run orílẹ̀-èdè jẹ́ àwọn òrìṣà, ṣùgbọ́n OLúWA dá àwọn ọ̀run.
I. Kro 16:26YCE(Yoruba Bible)
Nítorí pé ère lásán ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù sọ di ọlọrun, ṣugbọn OLUWA ló dá ọ̀run.
Pín
I. Kro 16YCE