Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 16:28YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ fi fun Oluwa, ẹnyin ibatan enia, ẹ fi ogo ati ipa fun Oluwa.
I. Kro 16:28BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fi fún OLúWA, ẹ̀yin ìdílé àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ fi ògo àti ipá fún OLúWA.
I. Kro 16:28YCE(Yoruba Bible)
Ẹ fi ògo fún OLUWA, gbogbo ayé, ẹ gbé ògo ati agbára wọ̀ ọ́!
Pín
I. Kro 16YCE