Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 16:29YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ fi ogo fun Oluwa ti o yẹ fun orukọ rẹ̀: mu ọrẹ wá, ki ẹ si wá siwaju rẹ̀: ẹ sin Oluwa ninu ẹwà ìwa-mimọ́.
I. Kro 16:29BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fún OLúWA ní ìyìn nítorí orúkọ rẹ̀; gbé ọrẹ kí ẹ sì wá síwájú rẹ̀. Sìn OLúWA nínú inú dídùn ìwà mímọ́ rẹ̀.
I. Kro 16:29YCE(Yoruba Bible)
Ẹ fi ògo tí ó yẹ orúkọ OLUWA fún un, ẹ mú ọrẹ wá sí iwájú rẹ̀! Ẹ sin OLUWA pẹlu ẹwà mímọ́
Pín
I. Kro 16YCE