Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

I. Kro 16:31YBCV(Bibeli Mimọ)

Jẹ ki awọn ọrun ki o yọ̀, si jẹ ki inu aiye ki o dùn; si jẹ ki a wi ninu awọn orilẹ-ède pe, Oluwa jọba.

I. Kro 16:31BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Jẹ́ kí àwọn ọ̀run kí ó yọ̀, jẹ́ kí ayé kí ó ṣe inú dídùn; lẹ́ kí wọn kí ó sọ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, pé “OLúWA jẹ ọba!”

I. Kro 16:31YCE(Yoruba Bible)

Kí inú ọ̀run kí ó dùn, kí ayé kí ó yọ̀, kí wọ́n sọ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè pé “OLUWA jọba!”