Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 16:36YBCV(Bibeli Mimọ)
Olubukún li Oluwa Ọlọrun Israeli lai ati lailai. Gbogbo awọn enia si wipe, Amin, nwọn si yìn Oluwa.
I. Kro 16:36BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olùbùkún ni OLúWA, Ọlọ́run Israẹli, láé àti láéláé. Lẹ́yìn náà gbogbo àwọn ènìyàn wí pé, “Àmín,” wọ́n “Yin OLúWA.”
I. Kro 16:36YCE(Yoruba Bible)
Ẹni ìyìn ni OLUWA, Ọlọrun Israẹli, lae ati laelae!” Gbogbo àwọn eniyan sì dáhùn pe, “Amin”, wọ́n sì yin OLUWA.
Pín
I. Kro 16YCE