Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 16:8YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa, ẹ pè orukọ rẹ̀, ẹ fi iṣẹ rẹ̀ hàn ninu awọn enia.
I. Kro 16:8BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLúWA, ẹ pe orúkọ rẹ̀, ẹ fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nínú àwọn ènìyàn fún ohun tí ó ṣe
I. Kro 16:8YCE(Yoruba Bible)
Ẹ fi ọpẹ́ fún OLUWA, ẹ képe orúkọ rẹ̀, ẹ kéde ohun tí ó ti ṣe fún àwọn orílẹ̀-èdè.
Pín
I. Kro 16YCE