Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

I. Kro 21:1YBCV(Bibeli Mimọ)

SATANI si duro tì Israeli, o si tì Dafidi lati ka iye Israeli.

I. Kro 21:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Satani sì dúró ti Israẹli, ó sì ti Dafidi láti ka iye Israẹli.

I. Kro 21:1YCE(Yoruba Bible)

Satani fẹ́ ta jamba fún àwọn ọmọ Israẹli, nítorí náà ó gbó Dafidi láyà láti kà wọ́n.