Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

I. Kro 28:10YBCV(Bibeli Mimọ)

Wò o nisisiyi: nitori Oluwa ti yàn ọ lati kọ́ ile kan fun ibi mimọ́, mura le, ki iwọ si ṣe e.

I. Kro 28:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Gbèrò báyìí nítorí tí OLúWA ti yàn ọ́ láti kọ́ ilé OLúWA gẹ́gẹ́ bí ilé tí a yà sí mímọ́ fún OLúWA. Jẹ́ alágbára kí ó sì ṣe iṣẹ́ náà.”

I. Kro 28:10YCE(Yoruba Bible)

Kíyèsára, nítorí pé OLUWA ti yàn ọ́ láti kọ́ ilé kan tí yóo jẹ́ ibi mímọ́, ṣe gírí, kí o sì kọ́ ọ.”