Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

I. Kro 29:10YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitorina Dafidi fi iyìn fun Oluwa li oju gbogbo ijọ: Dafidi si wipe, Olubukún ni Iwọ Oluwa Ọlọrun Israeli baba wa lai ati lailai!

I. Kro 29:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Dafidi yin OLúWA níwájú gbogbo àwọn tí ó péjọ, wí pé, “Ìyìn ni fún Ọ, OLúWA, Ọlọ́run baba a wa Israẹli, láé àti láéláé.

I. Kro 29:10YCE(Yoruba Bible)

Nítorí náà, Dafidi yin OLUWA níwájú gbogbo eniyan, ó ní: “Ìyìn ni fún ọ títí lae, OLUWA, Ọlọrun Israẹli, Baba ńlá wa