Ṣe àfiwé gbogbo èyà
I. Kro 4:9YBCV(Bibeli Mimọ)
Jabesi si ṣe ọlọla jù awọn arakunrin rẹ̀ lọ: iya rẹ̀ si pe orukọ rẹ̀ ni Jabesi, wipe, Nitoriti mo bi i pẹlu ibanujẹ.
Pín
I. Kro 4YBCVI. Kro 4:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jabesi sì ní ọlá ju àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin lọ. Ìyá rẹ̀ sì sọ ọ́ ní Jabesi wí pé, “Mo bí i nínú ìpọ́njú.”
Pín
I. Kro 4BMYOI. Kro 4:9YCE(Yoruba Bible)
Ọkunrin kan, tí à ń pè ní Jabesi, jẹ́ eniyan pataki ju àwọn arakunrin rẹ̀ lọ. Ìyá rẹ̀ sọ ọ́ ní orúkọ yìí nítorí ìrora pupọ tí ó ní nígbà tí ó bí i.
Pín
I. Kro 4YCE