I. Joh 1:9
I. Joh 1:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi awa ba jẹwọ ẹ̀ṣẹ wa, olõtọ ati olododo li on lati dari ẹṣẹ wa jì wa, ati lati wẹ̀ wa nù kuro ninu aiṣododo gbogbo.
Pín
Kà I. Joh 1I. Joh 1:9 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn bí a bá jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wa: olóòótọ́ ati olódodo ni òun, yóo wẹ àìṣedéédé gbogbo nù kúrò lára wa.
Pín
Kà I. Joh 1